KEERE 

Words and Music composed, written and arranged by Olusegun Akinlolu. No part of these lyrics should be shared in any form or any public space without giving credit to the writer. All rights reserved. © & ℗ 2014 EniObanke


 

1. ẸNIỌMỌSIN 
Oun ìyá rere nṣe ó pọ̀ l’ọ́rọ̀ ọmọ 
Wọ́n á tọ́ ni s’ọ́nà, wọ́n á kọ́ ni mọ̀ọ́ ṣe 
Wọ́n á ṣiṣẹ́ bí ẹni kì í rẹ̀ nígbàgbogbo 
Olùfẹ́ àkọ́kọ́, ìyá ni o 

Oun ìyá rere nṣe ó pọ̀ l’ọ́rọ̀ ọmọ 
Wọ́n á gbé ni jó o, wọ́n á rẹ ni l’ẹ́kún 
Wọ́n á ṣiṣẹ́ bí ẹni kì í rẹ̀ nígbàgbogbo 
Olùfẹ́ òtítọ́, ìyá ni o 

Oun ìyá rere nṣe ó pọ̀ l’ọ́rọ̀ ọmọ 
A bá ni s’ọ̀rọ̀ ìwúrí, a gbé ni ró o 
Nínú àìní àti ìkorò kì í da ni 
Olùfẹ́ àkọ́kọ́, ìyá ni o 

Oun ìyá rere nṣe ó pọ̀ l’ọ́rọ̀ ọmọ 
A mú ni mọ̀’nà òtítọ́ pẹ̀lú sùúrù 
Wọ́n á ṣiṣẹ́ bí ẹni kì í rẹ̀ nígbàgbogbo 
Olùfẹ́ òtítọ́, ìyá ni o 

Ẹni bí’mọ kó má yọ̀ jù 
Ẹni ò ì bí ìyẹn má ba ‘nú jẹ́ 
Ọba òkè ò gbàgbé ẹnìkankan 
Ẹni ọmọ sin ṣé yẹn ló bí‘mọ o 

(A good mother’s roles in a child’s life are invaluable 
She’s the pathfinder, the caregiver, the cheerleader 
Tireless, ever present on the job 
A good mother is a child’s first love. 

A good mother’s impact on a child’s life is incalculable 
She’s the mentor, the inspirational speaker, the gentle teacher 
She never gives up even in most dire adversity 
A good mother is a child’s true love. 

Do not over-jubilate when you have a child 
And those still waiting should not despair 
You can only lay claim to motherhood 
When your passing is celebrated by well-raised children.) 

2. WẸYINWO 
In this time we live in, this time we live in 
Time we live in, this time we live in 
You can’t always find a friend 
They’ll tell you to get your own bread 
And hope is not that easy 
Oh no, you can’t always find a true friend 
And it doesn't get any easier 

Ọ̀rẹ́ àjọjẹ o, wọ́n pọ̀ lóde o 
Ọ̀rẹ́ ojú ayé o, àwọn ná mà kún ‘ta o 
T’o bá ṣe rere o, inú wọn á bàjẹ́ o 
O ò gbọdọ̀ ní’lọsíwájú, wọ́n á máa ṣè’lara 
Bóo ṣe nwo ‘wájú, ko ya máa b’ẹ̀yìn wò o 
Ọ̀rẹ́ w’ẹ̀yìn, 
W’ẹ̀yìn rẹ, w’ẹ̀yìn rẹ, w’ẹ̀yìn rẹ - bóo ṣe nwo ‘wájú o 

W’ẹ̀yìn rẹ, w’ẹ̀yìn rẹ, w’ẹ̀yìn wò
 
(True friends are hard to find out there 
When you make progress, they get bitter and envious 
Keep your eyes on the future, but watch your back) 

In this place of shadows where dreams are born 
This house of illusion where dreams are shattered 
The truth may not be true 
The fittest rule with might 
And justice isn’t always served 
Oh no, reality may not be real 
And it doesn't get any easier 

Apálará, kọ ‘jú sí tìrẹ o 
Má w’ago aláago sáré, k’o dẹ̀ rọra ṣe o 
Ijọ́ tóo bá rí o, pèsè f’ọ́jọ́ àìní o 
Bóo ṣe nwo ‘wájú, ko ya máa b’ẹ̀yìn wò o 
Ọ̀rẹ́ w’ẹ̀yìn, 
W’ẹ̀yìn rẹ, w’ẹ̀yìn rẹ, w’ẹ̀yìn rẹ - bóo ṣe nwo ‘wájú o 

W’ẹ̀yìn rẹ, w’ẹ̀yìn rẹ, w’ẹ̀yìn wò
 
(Follow your own path, stop chasing shadows 
And when you have, remember to save for the day of lack 
Keep your eyes on the future, but watch your back) 

3. THE PATH 
I sing for the little ones 
For the women with their worries 
I sing for the old and tired 
Give the youth some hope and direction 
I sing for the downtrodden 
The beaten man in the gutter 
I sing for the powerful 
That they may be humble and learn to be kind 
Change will come to the one who is ready 
Face the truth and stand for justice 
Too many days of pain and sorrow 
Now is the time to make your move 

Gb’ọ̀nà àtúndá yẹn, ó yẹ kóo gb’ọ̀nà àtúndá yẹn 

Ó yẹ kóo m’ọ̀nà àtúnbí yẹn 

Ó yẹ kóo m’ọ̀nà yí o 

(Take that path of rebirth 

You should know that path) 

I sing for the high and low 
Of the ups and downs of life 
Make the journey easier 
For my brothers and sisters trapped in the struggle 
I sing of ancient wisdom 
To remind you in simple words 
If your neighbor is not happy 
There is no way you can be at peace 
Sow your life, your talent and energy 
Plant a tree today my sister 
Provide shade for future wayfarers 
Make this land better than we met it 

Don't you worry about me 
I’m just a flash of light passing through 
Find the strength to make the change 
And strive to be happy, strive to be free 
There’s no reason to wallow in sadness 
Stand up strong and raise your head 
For the day of reckoning cometh 
When we’ll be marching to the sound of freedom 
Change will come to the one who is ready 
Face the truth and stand for justice 
Too many days of pain and sorrow 
Now is the time to make your move 

4. SILENT NO MORE 
Some people have come here to sell 
Some people have come here to buy 
Some people come along just to watch them 
We share love 
We spread love 
We share love 

Some people have come here to build 
Some people have come here to grab 
Some people come along just to destroy 
We won’t be silent no more 
We spread love 
We won’t be silent no more 

Some people look up to the sky 
Waiting for a mighty deliverer 
Some people dig up all the riches 
We won’t be watching no more 
We spread love 
We won’t be watching no more 

Some people have come here to run 
Some people take it with no sweat 
There’s always someone looking to be smart 
We won’t be silent no more 
We will be standing in the light 
We won’t be silent no more 

5. OṢOMAALO 
B’ó sáré ma fò o, b’ó dẹ̀ rìn ma sáré 

Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọ̀bọ 
B’ó wọ’lé ma lòṣó o, ma dèrìgì pẹ̀lú eléyín 
Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọ̀bọ 
Wọlé o bá nmú nkan mi 
Gbèsè rẹ ni o máa sán 

B’ó pọ́n’gi ma tẹ̀le, b’o wẹ̀’kun ma wọ’nú ibú 

Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọ̀bọ 
B’ó mú ‘nú aginjù lọ, ma fi ìgboyà wọ’nú igbó 
Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọ̀bọ 
Wọlé o bá nmú nkan mi 
Gbèsè rẹ ni o máa sán 

(If he runs, I will fly and if he walks, I will run 

To trap an ape, a hunter must think like one. 

If he hides in his house, I will squat at the door 

I will stick to him like gum to tooth. 

Now go in and get my thing 

It’s your debt and you must settle it. 

If he goes up a tree, I will climb along 

And if he swims the ocean, I will dive in 

To trap an ape, a hunter must think like one. 

If he runs to the forest, I will bravely follow 

To trap an ape, a hunter must think like one. 

Now go in and get my thing 

It’s your debt and you must settle it.)
 

6. HOUSE BY THE SEA 
Martha paints, paints, paints 
Sitting all alone, in her little house by the sea 
And every moment passing brings him closer still 
And soon he’ll be coming home. 

Martha sews, sews, sews 
Makes a little quilt, in her little house by the sea 
And every door that's creaking brings a little smile 
That soon he’ll be coming home. 

Martha prays, prays, prays 
By her dainty crib, in her little house by the sea 
Cos every word of the letter makes it plain and clear 
He won’t be coming home no more. 

Martha dusts, dusts, dusts 
Cleans up every inch of her little house by the sea 
Cos when they bring the body, it will be like a king 
Laying on a golden bed. 

Martha waits, waits, waits 
Counting up the stars above her little house by the sea 
And every distant twinkle, like his gentle hand 
Wipes away her silent tears. 

Martha’s grey now 
Sitting all alone in her little house by the sea 
And every moment passing brings her closer still 
To the one she loves the most 

Martha’s gone now… 

7. TEWỌGBARE 
Tẹ́wọ́gbare yé o 
Tẹ́wọ́gbare yé, ire nbọ̀ l’ọ́nà 
(Open your hands to good fortune) 

Man working hard all his life 
Doing everything to be justified 
But the crooked system mocks and pulls you down 
You’re not alone, payback is coming 

Woman sowing good seeds in the land 
Planting for the present and the future 
And your heart is broken by the growing darkness 
Put on a smile, reward is here now 

Tẹ́wọ́gbare yé o kò ní fò ẹ́ 

Ẹní nṣiṣẹ́ ṣe b’óun ló yẹ kó j’ọrọ̀ n’ílẹ̀ yí o 
(Open your hands to good fortune 
Those who toil deserve the wealth of this land) 

Brother toiling hard in the sun 
Looking to the best for the children 
But the questions mount and there are no answers 
Relax your mind, payback is coming 

Sister with the broken heart 
Sadness is the lot of the weary 
I know you’ve done your best but no one understands 
Wipe off the frown, reward is here now 

8. RE-AWAKENING 
We’ve been lying in stasis 
Failed to do what we ought to do 
Spirits dying, voices croaky with disuse 
We’ve been deserting our lines 
Evil forces riding over us 
Break the chains, lead the prisoners into the light 
Re-awakening - we’ve got to get up 
Rejuvenation - we’ve got to move on 
Resuscitate - we’ve got to get up 
And move on… 

Roll the drums, give me a beat 
Blow the horns, set the mood 
O ye maidens, raise your voices and sing loud 
It’s the day we’ve been waiting for 
Father Sun shining up above 
Mother Earth warming up to the rhythm of change 

9. KEERE O! 
Àdan d’oríkodò, ó mí wò ‘ṣe ẹyẹ 
Tẹníbẹ́gi ló jù, ṣèb’ígi á rú ‘wé 
Ẹ má rò wọ́n pin o, ẹni ò rí ṣe l’òní 
Kò s’ẹ́ni t’ó m’ọ̀la o, ìgbẹ̀yìn l’aláyò nta o 
Kérè o, ọba ló ní a ki yín 
Wọ́n ní ẹ má ṣ’ọ̀lẹ o, ẹ múra sí ‘ṣẹ́ ajé 
Kérè o, ìjòyè ṣe yín pẹ̀lẹ́ 
Wọ́n ní ẹ má ṣ’àfara, ẹ jẹ́ a tún ‘lẹ̀ yí ṣe 

Ẹ bá nké sí wọn o, àwọn a fòró ìlú, 
Akótilétà l’ọ́pọ̀, ọ̀tá a ṣe bí ọ̀rẹ́ 
T’ẹ bá f’etí s’ílẹ̀, ṣèbí ‘rọ́ àtọdúnmọ́dún 
Òun ni wọ́n nrò l’ọ́bẹ̀, tí wọ́n fi nrùn wá n’ímú 
Kérè o, àgbà ló ní a kí yín 
Wọ́n ní ẹ má gbà mọ́, k’ọ́mọ àpà tún borí 
Kérè o, ará ọ̀run t’àjò dé, 
Wọ́n ní a b’áwọ̀n l’ọ́rùn, ka d’òmìnira tòótọ́ 

Àdan d’oríkodò, ó mí wò ‘ṣe ẹyẹ 
Ọ̀rọ̀ yí ndé kùn d’áyà, t’ó bá yá ojú á k’ojú 
Kérè o, ọba ló ní a ki yín 
Wọ́n ní e má ṣ’àníyàn, ká ṣ’ayé ‘re kó yẹ wá 
Kérè o, ará ọ̀run t’àjò dé, 
Wọ́n ní ẹ b’ókùn l’ọ́rùn, ka d’òmìnira tòótọ́ 

(The bat hangs up side down, watching the ways of birds 
Pay the logger no heed, the tree will flourish again 
Sneer not at those who have fallen behind 
The race is far from over. 
Harken! The king sends his greetings 
Says we should keep working hard to build this economy 
Hear, hear, the chiefs send their warm wishes 
They say we must act fast, restore the glory of this land 

Now, let’s call on them 
Those who have brought sorrow upon the land 
Betrayers of communal trust, 
Enemies under the cloak of gay smiles 
If you listen carefully, it is the same platter of ageless lies 
That they have come to serve again. 
Harken, the elders greet you, 
They say, this time, we must resist these prodigals 
Hear, hear, ancestral spirits descending 
They say we should remove the chains from around our necks 
And enjoy true freedom. 

The bat hangs up side down, watching the folly of birds 
This anger, rising 
Soon, it will reach boiling point.) 

10. AFI’RE 
Ibi orí dá ni sí làá gbé o Akin ọmọ 
Ibi a gb’ẹ́sẹ̀ lé nló yẹ k’ẹ́sẹ̀ tọ̀ 
Ibi orí dá ni sí làá gbé o 
Ibi a gb’ẹ́sẹ̀ lé nló yẹ k’ẹ́sẹ̀ tẹ̀ 
Orí rẹ à fi’re, ẹsẹ̀  wo ‘bi ire gbé o wọ̀ láyé o 

Orí rẹ à fi’re, ẹsẹ̀ ibi ire ni o wọ̀, o ò ní ṣì’nà láíláí 

O ti já’wé olúborí o, Akin ọmọ 
O d’ẹni à jí rí, a dùn-ún wò 
O ti já’wé olúborí o, ọmọ àgbà tí nso làákàyè 
Lè ṣ’ẹbọ, lè ṣoògùn l’áyé 
B’á ṣe w’áyé páá rì́ làá rí o 
Ò bá dè lè ṣ’ẹbọ k’o ṣ’ògùn tó gbóná 
Iṣẹ́ ọwọ́ ẹni ṣe yen ní gbé ni l’ékè l’áyé 

(You flourish where destiny plants you 
Legs should always move as directed 

You flourish where fate leads you 

Feet should always step where the owner wants 
May your head guide you to good fortune 
May your tread lead you to good places 

You’ve made the ranks of the valiant 
You’ve become the beloved of the people 
Well-groomed soul bearing fruits of wisdom. 
Try as we may, 
We can only be what we were meant to be 
Try as you may 
We will eventually be judged by the works of our hands)

11. ADIITU 
À ì lè ní sùúrù o, ṣe b’óun ló ndàmú àwa o 
Ṣùgbọ́n ẹni tó bá l’áforítì, ó dájú 
Òun ni yó d’aṣẹ́gun 
Àdììtú layé yìí o, kò s’ẹ́ni tó mà yé o 
Ṣùgbọ́n t’a bá nfì’fẹ́ lò pọ̀, ó dájú 
Ayé wa yó dùn 

T’ó bá yá, ìgbà t’ó bá yá, ará mi o 
Èbù ìkà tí a gbìn y’ó s’èso 
T’ó bá yá, láìpẹ́ ọjọ́ ọ̀rẹ́ mi o 
Ìwà ìbàjẹ yìí o, y’ó mà lẹ́yìn 
T’ó bá yá, àní t’ó bá yá ọ̀rẹ́ mi o 
Ohun àkólọ o, y’ó da’rí bọ̀ 
T’ó bá yá, t’a bá nṣ’iṣẹ́ àtúnṣe o 
Ìbùgbé ayọ̀ y’ó d’ọ̀tun 

Ká rìn ká pọ̀ ní yẹ ni 
Ká f’ọwọ so ‘wọ́ pọ̀ k’ó lè da o 
Ṣèb’ọ́wọ́ kan ò gb’ẹ́rù d’órí ọ̀rẹ́ mi, ẹ jẹ́ ká jọ ṣe pọ̀ 
Ìlara pẹ̀lú tẹ̀mbẹ̀lẹ̀kun 
Ṣèb’áwọn ná nda ‘lé ọlá rú 
Òtítọ́ ni ó gbé wa lékè, ó dá jú 
Ẹ jẹ́ ká so ‘wọ́ pọ̀ 

(Impatience is our bane 
But those who persevere will definitely succeed 
Life is an insoluble puzzle 
But if we commune in love, we shall surely find happiness 

In time, the evil we have sown will blossom 
In due course, we shall reap the fruits of our waywardness 
In time, what has been lost will be restored 
In due course, the home of joy will be renewed 

There is strength and prominence in numbers 

One hand is inadequate to lift a load up on the head 

Let us work together to make things better 

Bitter jealousy and treachery destroy the bond 
Truth, surely, will elevate us 
Let us work together) 

12. BEYOND THE GRAY 
Early morning, in your moment of longing 
I’ll be waiting there for you 
When the darkness spins a web of worry 
I’ll be watching out for you 

Burn your heartaches, leave the ashes in the past 
Walk the sunlight shinning bright in the sky 
Embrace joy 
And any moment when your heart is lonesome 
I’ll be reaching out for you 

When desire lights a fire in the night 
Raise your offerings to the goddess of passion 
And be still 
Cos in a moment, just beyond the gray light 
I’ll be standing there before you 
And anyday now, when you’ve crossed the river 
I’ll be waiting there for you.

Leave a comment